Olubusayo Oladipo – Wo Ki O Riye

- Olubusayo Oladipo – Wo Ki O Riye
Song Duration: 00 Hr 04 Min 29 Sec
Downloaded 1042 times Played 923 times File Size 4.26 MB 4.26 MB

Debutante gospel music minister, Olubusayo Oladipo, makes an astonishing and gallant entry into the gospel music scene with a brand new single and lyric video titled “Wo Ki O R’iye” produced by Odunayo Aboderin.

Delivered in both English and Yoruba languages, the Yoruba titled song which translates as “Look And Live” embodies the testimonies of Olubusayo’s personal encounter with God in order to encourage believers to keep their focus on Christ and also to bring many others to the knowledge of Christ.

[Lyrics]

Chorus:
Wo o ki o r’iye
Wo Jesu ki o r’iye
Wo o ki o r’iye
Wo Jesu ko d’asegun

Verse
1:
Iku oro re lori igi
L’o fun mi ni iye
O so mi d’omo
Mo r’iye gba ninu Oluwa

Ide mi ja o mo yege
Tori mo wo o mo r’iye
(ore mi)

Solo 2:
Okunkun d’opin o
Ija d’opin
Imole mi tan iye
Iye mi de,

Kristi ninu mi
Ireti ogo mi
Orin halelujah ni mo nko
Olurapada lo ra mi pada

Mo dalayo mo sorire
Olurapada lo ra mi pada
Mo r’iye gba, Mo j’asegun lo

I’ve a message from the Lord,
Hallelujah!
The message unto you I’ll give
‘Tis recorded in His word,

Hallelujah!
It is only that you “look and live”

Look and live my brother live
Look to Jesus now and live
‘Tis recorded in His word,
Hallelujah!

It is only that you look and live

Wo k’o ye, Arakunrin
Wo Jesu ki o si ye
A ko sinu oro re
Aleluya

P’eni t’o ba wo Jesu y’o ye

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *