Lara George – Ijoba Orun

Ijoba Orun Lara George
Downloaded 9265 times 9265 Played 2471 2471 File Size 5.85 MB 5.85 MB

Ijoba orun, lere onigbagbo o
Ma jen kuna baba, mu mi dele o
Ki n ma ku sajo, bii eefin
Mu mi dele

[Lyrics]

Ijoba orun, l’ere onigbagbo o
Ma je’n ku’na baba, mu mi de’le o
Ki n ma ku s’ajo, bii ee
fin
Mu mi de’le

Owo ti mo ni
Ko le mu mi de’le o
Moto ti mo ri ra
Ko le wa mi de’le o
Ore ti mo ni
Ko le sin mi de’le o
Gbogbo iwe, ti mo ri ka
Ko le gbe mi re’le o

Ma je n ku’na baba
Mu mi de’le o
Ki n ma ku s’ajo, bii eefin
Mu mi de’le o
Aye l’oja, orun n’ile
Mu mi de’le

Yoruba, Posted on

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *